I. Tani Adamu / Who was Adam?
Ninu
Bibeli, iru orisi Omo bii meta lo wa. Bibeli laa ye wa wipe :-
1.
Adamu, Omo ti a da (The created son) (Luku 3:38);
2.
Jesu Kristi Omo bibi kan soso (the only begotten son of God)
(John 3:16; Luku 2:11); ati
3.
Omo eyin Kristi, awon ti a so dOmo(Christians are adopted children of God)(Roman 8:23;9:4; Galatia 3:26; Ephesians 1:5.)
Adamu je Omo
Olorun ti a da. Lati ipase Adamu, opo nkan lo sele ti o pagidina Ibare, Ibarin
ati alafia awa eniyan pelu Olorun (Romans 3:23; 5:1-2). Lara awon nkan ti o
sele wonyii so eniyan di eniti o ru ibinu Olorun soke. Eniyan ba ara re ninu
kootu Olorun(Genesisi 3:9 -19) ni alae ri tabi ri alagbejo ro (Advocate).
Eniyan di eni irira, iyapa ati egbin si Olorun Eleda re. Eyi ni ipo ti eniyan
ati aye wa si Olorun. Ko si te Olorun lorun. Lati igba naa wa, ni Olorun ti nwa
ona lati mu eniyan pada sodo ara Re.
II. Tani Jesu Kristi / Who is
Jesus Christ
Jesu
Kristi ni Olugbala Jesus (Christ is the Messiah); Omo Olorun (the son of God) – Matt. 1:16, 21; 16:16. The same
yesterday, today and fo ever (okan naa
lana, loni ati titi aye) Heb. 13:8; 1:3
III. BIBELI KIKA (Romu 5.12-21).
Se afayo bi iku se wonu aye ati bi iye se
wonu aye nipase Adamu ati Jesu kristi.
Adamu (Apere eniyan) Jesu
Kristi (Olugbaala eniyan)
(vs12 – 14) (Vs
15 -16)
Ese wonu aye nipase Adamu. Ninu
Jesu Kristi ebun oore ofe pupo wonu aye
Ofin ati iku nitori ese wonu aye Ninu Jesu Kristi idalare wonu aye.
V. 17 Nipase Adamu iku joba Nipase
Jesu Kristi iye ti konipekun joba.
V. 18 Nipase Adamu idajo idalebi Nipase Jesu Kristi idajo idalare.
V. 19 Nipase Adamu aegboran joba Nipase Jesu Kristi igboran ninu ododo di
pupo.
V. 20 Nipase Adamu ofin n muni jabo Nipase Jesu Kristi oore –ofe nifa ni losoke tabi di
pupo
V. 21 Nipase
Adamu ese n joba si iku Nipase
Jesu Kristi, oore –ofe n joba sinu ife
ati iye aenipekun Olorun.
Akiyesi.
1. Itan Adamu ni a nka loni, Ise Igbala ti Jesu Kristi ti
pari fun iran
eniyan “ko ti, bee ni ko si sa’. Ise
Igbala yii lo yo enikeni ti o ba gba Jesu Kristi gbo kuro ninu ogbun ibinu
Olorun ti mba yorisi iku ati Orun apadi.
2. Aeni Omo Olorun (Jesu Kristi) ko jeki eniyan ni IYE.
Aeni iye le mu eniyan padanu iye aenipekun. Eyi le mu ki eniyan ku iku ti ara,
ku iku ti emi, ki o si tun ku iku ayeraye (I John 5:6 -12)
3. Niwon igbati Adamu ti kuro ninu aye anfani wa fun iwo ati emi lati fi
igbagbo wa ro mo IYE ninu Jesu Kristi. Ki a gba a, ki a lo o (Romu 11:31 -32)
ati ki a si duro sinsin ninu Re.
4. Bi aye wa ko ba ti ri bi o se ye ki ori, eyi ko wipe
aye titun
ninu Jesu Kristi soro lati gbe. O ye ki a gbe igbe aye wa bii eniti Iye Jesu
Kristi ngbe inu re. eyi yoo mu wa gbe igbe aye igboran si Olorun nipa bibori
tabi yiya go fun ese; sisan idiyele tabi irubo ninu irin ajo Igbagbo yoo rorun
fun wa lati se (Romu 8:12 -17) lati kede Ihinrere ninu oro ati ise wa yoo si
leke ohun gbogbo. (Romu 1:16)
Akoko Adura.
1.
Mase jeki ise ati
aye Adamu tun ma jeyo ninu aye mi. jowo ran mi lowo, mu mi bori eran ara.
2.
Mase jeki awon
agbekale miran ti mo le se abapade ninu aye mu mi sina ijoba Re Oluwa.
3.
Oore – ofe ti n
go fifi gbogbo ojo aye mi sin O, kede Ihinrere ati ribi desi ni ile ologo je
ipin mi.
4.
Bi aye ba daru,
ti ko si ni itumo, mase jeki n je eni ti yoo ma da aye ru. Gba mi lowo adaye
eni ru.
No comments:
Post a Comment