Ifaara: Igbe aye igbadun eni maa n soro gan – an ni lati fi
sile, Eniti o ni oko tabi ohun irinna miran; eniti o ni Ile, ti ko wa ni mo;
eniti o ni ise lowo ti ko wa ri ibikankan lo mo a.b.b.b.l bi iru eni bee ko ba ni AJE – ARA (Immunity), o le di elomiran (Onidajo 16:17 --- alaelera,
emi si dabi Okunrin miran)
Bibeli Kika (Romu 6:15 -23)
(Vs 15 -18). Se afayo bi
Kristiani se ri labe Oore – ofe, ti ki si se labe ofin.
a.
Nitori ti a wa labe
oore –ofe ko wipe ki a maa dese – (V15).
b.
Nitori ohunkohun ti a a ba yonda fun la o maa gbo lati
se tire
c.
Bi a ba yonda ara wa fun ese le yorisi iku, ofin ni yoo
si se idajo ara (v16)
d.
Bi a aba yonda ara wa fun igboran le yorisi ododo, oore
– ofe yoo si mu wa duro
e.
Oore – ofe ti so wa di ominira kuro ninu ese, ki i se labe ofin ki a le maa se ododo
(Vs. 17 18)
(Vs. 19 – 23). Se afayo bi Omoeyin
Kristi se le gbe igbe aye ododo, ti o le soo di olododo.
1.
Bi awon iwa ese ti ndun mo o, bee gege ni yoo di eru si
igbe aye ododo ninu Kristi – (V19)
2.
Bi a ko ti mo Omo-eyin Kristi nigbati o wa ninu ese, bee
gege la o mo o ninu ododo – (V20)
3.
Bi a ko se tiju ninu ese dida, bee gege la ko gbodo
tiju lati gbe igbe aye ododo – (V.21)
4.
Bi a se so wa di ominira kuro ninu ese, bee gege eso
iwa mimo wa yoo yori si iye aenipekun (V22)
5. Bi
iku se je ere fun es, bee gege ebun Oofe Olorun yoo je ere si iye aenipekun –
(23).
AKIYESI.
1.
Eko wa oni n laaye wa wipe - eniti a n ba ngbo tire ni
yoo je oga, aladari tabi alase lori aye wa. Bi o ba je owo, owo ni yoo maa dari
wa tabi bi o ba je nkan miran nkan miran bee ni yoo ma je oga ati alase lori
aye wa.
2.
Eko yii n ran wa leti wipe gbigba ti a gba wa la. Oore
– ofe lati gba wa la kii se ofin tabi ise ti a ba maa fi sogo (Efesu 2:4 - 9)
3.
Bi ofin ba n sise idajo, idalebi, ti oore –ofe si n
sise idalare. O je wipe ebun oore – ofe yii di ohun elo iwa si ododo ti o le so
wa di olododo ki a le jere olododo (Matteu 10 :40 – 42; Heb. 6: 9 -12)
4.
Gbogbo eniyanloni ominira lati yan eyiti o wu – u.
Olorun kii mu enikeni ni tipa – tipa lati se ti Oun. Olorun je Alaanu
nitori Ijolododo Re, bi a ba se fi okan
ope wa gba ebun ofe Igbala re si tabi de la o je ere ati Igbadun ebun oore ofe
Re (Deut. 30:15 - 19)
5.
Gba Jesu Kristi sinu aye Re, bi aye ba buru, ko ye ki
Orun ko tun buru fun O. loni lojo Igbala re. ola le pe ju fun o. (Acts. 16:31;
Luku 19:8 - 10)
AKOKO ADURA.
1.
Oluwa gba ma se jeki nfi aye mi ba Orun mi je.
2.
Mase jeki n de Orun mo ottito
3.
Mase jeki ebun ofe naa bomo mi lowo tabi sii lo kuro
laye mi.
4.
Awon ti ko tii mo, ki won o le mo O ni Oluwa ati Olorun
won.
5.
Ninu ile Olorun wa maa joba n so.
6. Ni
Orile ede yii,
maa gba okunkun laye lati bori imole Re Oluwa.
No comments:
Post a Comment