(Hosea 3: 1 – 5)
(Ese .1 – 3) – Se agbeyewo bi Hosea se tun to Gomeri lo fun atunse.
1. Oluwa
wi fun –un pe ki o lo si odo obinrin re ti o se pansaga lo.
2. Nitori
ti o yi pada si Olorun miran, o si tun n fe akara eso ajara.
3. Nitori
o ti raa fun ara re ni fadaka meedogun ati homer baili kan ati aabo.
4. Ki
o wi fun – un pe yoo baa gbe lojo pupo.
5. Ki
yoo si huwa agbere re, ki yoo je ti Okunrin miran mo.
(Ese. 4 – 5) – Sise atunse ti Hosea
yoo se atunse pelu Gomeri je apere.
1. Ni
Ojo Pupo ni awon Omo Israeli yoo gbe laeni Oba, Olori a.b.b.l.
2. Leyin
naa, awon Omo Israeli yoo pada wa Oluwa Olorun won.
3. Dafidi
Oba won ati awon naa yoo beru Olorun ati ore Re lojo ikehin.
Akiyesi.
1. Olorun
ko so ireti Re nu lori elese nigba kankan.
2. Bi
elese ti osako lo ba ronu piwada nitooto Olorun yoo si tun tewo gbaa.
3. Kii
se ohun ti o dara fun eniyan (Omoeyin Kristi) ki o maa mu ese bi eni mumi, labe
wipe, Olorun yoo darii Oun. Iru Igbese bee le yori si ese amomo da ti ko ni
idariji.
Akoko Adura.
1. Oluwa
nigbati mo ti jewo Re ni OLUWA ati Olugbala aye mi mase jeki n boju wehin.
2. Ranmi
lowo, ki apada si buburu mase de ba mi lona mi gbogbo
3. Ya
aye mi ya iwa ese ki iyoku aye mi je fun Ogo ati ola Re.
4. Odun
2013, jeki o dara fun mi ju ti ateyin wa lo
No comments:
Post a Comment