Sunday, August 25, 2013

GOMERI: APERE AGBERE ISRAELI


Bibeli: (Hosea 2: 1 – 5; I Korinti 10: 1 – 13)
 

(Ese.1 – 3 ) – Se afayo bi Olorun se pe awon Omo Gomeri si akiyesi iwa iya won– Apere esun agbara - I.
1. E wi fun arakunrin yin Ammi (1: 8 - 9) ati fun arabirin yin Ruhama – (1:6)
2. E ba iya yin wijo nitori oun kii se aya mi, emi ki ise oko re.
3. Nitori naa ki o mu gbogbo agbere re kuro ati pansaga re kuro larin oyan re.
4. Ki emi maa ba tuu si ihoho bi ojo ti a bi i.
5. Emi o si gbe e kale bi ile gbigbe, wmi o si fi oungbe paa ku.

(Ese. 4 – 5) – Se afayo bi Olorun se pe awon Omo Gomeri si akiyesi iwa iya won – Apere esun bi ese O
bi o se le di ti Omo - II.
1. Emi ki yoo si saanu fun awon Omo re, nwon je omo agbere.
2. Nitori ti iya won huwa pansaga obinrin.
3. Entiti o loyun won ti se ohun itiju (nipa pipada si aye agbere – nitori ti o ran ti aadun ti n be nibe).

Akiyesi.
1. Olorun wa je Eniti n ma fi aye sile fun gbogbo eniyan lati ri ara won he nigbati n won ba ye kuro loju ona fun ironupiwada. (Orin Dafidi 19: 11 – 13)
2. Igbese miran ti Olorun ma n gbe ni wipe, O maa fi ohun ti a ri se apere fun wa ki eniyan ba le tete yipada ki o ma ba si awawi (Itan oninakuna kuna omo   - Luku 15: 17 – 21)
3. Lokan Olorun, ko fe ki a fi elomiran tabi nkan ropo Oun ninu okan ati aye wa. Ifi ejo tabi esun kan Gomeri  niwaju awon Omo re je apere fun wa loni. (I Korinti 10: 1 – 13)
4. Yiya kuro lodo Olorun tabi kuro lona Re ma n je ohun ti o le pagidina siso Ibukun eni di pupo ati anfani miran gbogbo. Ki eyi maa ba ri be ni eko yii se se pataki fun wa lati koo (Heberu 4:1 – 2 )


No comments:

Post a Comment